Ta ló kú? (Who died?) — A poem by Ayọ̀ Adams Ta ló kú? Ọmọ ẹnìkan kọ́ o Ẹ̀dùn ọkàn mi ló gun òkè nla kan lọ tó jábọ́ Òhun nìkan ló jábọ́, gbogbo ara ní ń ro alára Ẹjọ́ fi ẹlẹ́jọ́ sílẹ̀, ó gbá alápẹ́pẹ́ lójú Ta ló kú? Ọmọ ẹnìkan kọ́ o Ìgbẹ́kẹ̀lé mi nínú ènìyàn ni Bí wọ́n bá hàn ọ́ ní èèmọ̀ tán Ọmọ aráyé á tún ni, kílódé tí ò ń sunkún? Àjàlá ta ń ná ọ̀? Ẹ̀yin náà kọ́hun? Ta ló kú? Ẹnìkan kọ́, ọ̀rọ̀ ayé ní n gbá omijé lójú gbogbo wa.
Articles by Ayomide Adams
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams - (Ep. 3)
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams — (Ep. 3) “Olólùfẹ ni èmi àti Èyíwùmí ni ìgbà ti a wà ní Yunifásìtì Ìlọrin. Òdú sì ni ọ̀rọ̀ ìfẹ́ àwa méjèèjì, kìí se àìmọ̀ fún ẹnìkan ni ìgbà náà. Èyíwùmí fi ẹwà tó tàn yòò bí i ọjọ́ wùmí. Ìwà rẹ̀ tó tutù minimini bi àdàbà ló jẹ́ kí n fi ayé mi fún bíi olùgbàlà. Bí ẹ bá rí Èyíwùmí, ẹ ti rí mi.
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams - (Ep. 2)
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams — (Ep. 2) “Kíni o ṣẹlẹ̀ gangan ní Èjìòkú?” mo bèrè lọ́wọ́ Láànì bí mo ti n kọ ǹkan sínú ìwé tí mo fí n gba ọ̀rọ̀ sílẹ̀. Láànì n fi ọwọ́ ra àpá tí ń bẹ ní iwájú orí rẹ̀ ni ẹ̀kọ̀kan. Ó mí kanlẹ̀ bíi ọkọ̀ tó yọ ọwọ́ iṣẹ́ l’ójijì. Àyà mí já, mo ní, “Misita Láànì, are you sure you want to talk about this?” “Ajíláàláọ̀ṣọ́, ìnáwó ìgbéyàwó àwọn ọ̀rẹ́ wa kan ni mo lọ ni Kúdẹtì ni ìgbà kan báyìí.
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams - (Ep. 1)
“Ajíláàláọ̀ṣọ́, ni ọjọ́ tí wọ́n jí mi gbé, ọ̀nà Èjìòkú ni mo ti ń bọ̀. Ìrìn àwàsá ni mo rìn ni ọjọ́ náà, mo gbà. Sùgbọ́n, se ajínigbé a ò jínigbé ni ọ̀rọ̀ mi wá kàn? Ọ̀dọ̀ ọkọ arábìnrin tí mo lọ bá ní àjọṣepọ̀ ni ọkàn mi kọ́kọ́ lọ, ó dàbí pé òun ni ó ṣe ètò Ìjàmbá àgbákò yìí fún mi.” Láànì dá’nu dúró, ó gbé ife tó wà ní iwájú rẹ̀, ó sẹ́ omi díẹ̀ mu. Mo tẹ ojú mọ́ọ, mo n wo apá tìpọ̀ntipọn tó lé góngó ni orí rẹ̀.
Six Yoruba Movie Classics You Should See Again
Yoruba Nollywood industry has consistently served us premium entertaining contents since its started taking shape after the end of the Alarinjo Traveling Theatre Era. With advancement in technology and continuous invention of various creative approaches, the industry has successfully reached its peak and stands toe to toe with other film industry of the world including Bollywood and Hollywood of India and United States of America respectively.
Abeni Agbon: A look at Toyin Oladiran’s Image
Abeni Agbon: A look at Toyin Oladiran’s Image Toyin Oladiran is a Nollywood veteran actress who would confidently boast of a theatre career spanning more than two decades. From sneaking out of her house to savor the creative spice of her favorite drama shows featuring Baba Sala, Baba Mero and their contemporaries on Television in the next compound to leading Drama troupe in her secondary school, Toyin had found her passion in the Theatre Arts from quite a young age.
Eda Onileola: Singing praises of a theatre icon
Chief Olalere Osunpaimo who is popularly known and celebrated as Eda Onileola is one of the leading creative artists of the last two decades. He got his popular name ‘Eda’ through his contribution in the production of Duro Ladipo’s Yoruba Opera, Eda where he played the eponymous character. Eda (Everyman) is a morality play, originally a script in English but translated to Yoruba when it was brought to Ladipo’s Theatre by Ulli Bieir and wife, Susanne Wenger.
Eda Onileola: Singing Praises of a Theatre Icon
Chief Olalere Osunpaimo who is popularly known and celebrated as Eda Onileola is one of the leading creative artists of the last two decades. He got his popular name 'Eda' through his contribution in the production of Duro Ladipo’s Yoruba Opera, Eda where he played the eponymous character. Eda (Everyman) is a morality play, originally a script in English but translated to Yoruba when it was brought to Ladipo’s Theatre by Ulli Bieir and wife, Susanne Wenger.
Idanre Hills: Exploring the gift of nature in Ondo state
For weeks, we had embarked upon planning a trip to Idanre hills- the grand blessing of nature that sits majestically in its overwhelming glory in the town of Idanre, Idanre local government, Ondo state. Idanre, a town which is few kilometers away from Akure, the capital of Ondo state rest its settlement at the feet of the gigantic ‘Idanre Hills’.
Ibadan in the Time of Warriors: Who is Baale Irefin? » Opinions » Tribune Online
Baale Irefin, Ogundeyi was born at Owu several years ago. His father, Ogunlade who was a courageous warrior had migrated with his family to Ibadan and would later settle at the hill top known as Irefin today in the 18th century, just as other war lords who founded Ibadan. Ogundeyi’s father had in his control several slaves and servants which pronounces his noble status.
Ibadan in the Time of Warriors: Who is Baale Irefin? — Ayo Adams.
Ibadan in the Time of Warriors: Who is Baale Irefin? — Ayo Adams. Baale Irefin, Ogundeyi was born at Owu several years ago (No accurate account of his birth date). His father, Ogunlade who was a courageous warrior had migrated with his family to Ibadan and would later settle at the hill top known as Irefin today in the 18th century, just as other war lords who founded Ibadan. Ogundeyi’s father had in his control several slaves and servants which pronounces his noble status.
Exploring Nigeria's untapped tourists' destination
From the city of Ibadan to Ado Awaye, a town in Oke-Ogun area of Oyo State, Tour Ibadan, a tourism community of young individuals enthusiastic about the future of tourism in Nigeria and beyond, explored the mystery hills of Ado Awaye said to be home to the second hanging lake in the world – the other hanging lake being the one at Colorado State in the United States of America.
Show More
loading
Actions
Is this you?
As a journalist, you can create a free Muck Rack account to customize your profile, list your contact preferences, and upload a portfolio of your best work.Get in touch with Ayomide
Contact Ayomide, search articles and posts on X, monitor coverage, and track replies from one place.
Learn more about Muck Rack